Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
080

'Abasa 80:23 كلا لما يقض ما امره ٢٣

80:23
كـَلَّا
لَمَّا
يَقۡضِ
مَآ
أَمَرَهُۥ
٢٣
Rárá o! Ènìyàn kò tí ì ṣe n̄ǹkan tí Allāhu pa láṣẹ fún un.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Refutation against Whoever denies Life after Death

Allah rebukes those who deny the Resurrection and the Final Gathering.

قُتِلَ الإِنسَـنُ مَآ أَكْفَرَهُ

(Qutila mankind!) Ad-Dahhak reported from Ibn `Abbas that he said,

قُتِلَ الإِنسَـنُ

(Qutila mankind!) "May man be cursed." Abu Malik also made a

…

The Refutation against Whoever denies Life after Death

Allah rebukes those who deny the Resurrection and the Final Gathering.

قُتِلَ الإِنسَـنُ مَآ أَكْ
…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 80, Page 585, Juz 30

17. Wọ́n ti fi ènìyàn gégùn-ún (nípa) bí ó ṣe jẹ́ aláìmoore jùlọ! 18. Kí sì ni Allāhu fi ṣẹ̀dá rẹ̀? 19. Nínú àtọ̀ l’Ó ti ṣẹ̀dá rẹ̀. Ó sì pèbùbù (ẹ̀yà-ara) rẹ̀. 20. Lẹ́yìn náà, Ó ṣe ọ̀nà àtiwáyé ní ìrọ̀rùn fún un. 21. Lẹ́yìn náà, Ó máa pa á. Ó sì máa fi sínú sàréè. 22. Lẹ́yìn náà, nígbà tí Allāhu bá fẹ́, Ó máa gbé e dìde. 23. Rárá o! Ènìyàn kò tí ì ṣe n̄ǹkan tí Allāhu pa láṣẹ fún un. 24. Nítorí náà, kí ènìyàn wòye sí oúnjẹ rẹ̀. 25. Dájúdájú Àwa ń rọ òjò ní púpọ̀. 26. Lẹ́yìn náà, A mú ilẹ̀ sán kànkàn. 27. A sì mú kóró èso hù jáde láti inú rẹ̀; 28. àti èso àjàrà àti kànnáfùrù, 29. àti igi òróró Zaetūn àti dàbínù, 30. àti àwọn ọgbà tó kún fún igi, 31. àti àwọn èso (mìíràn) pẹ̀lú ewé tí ẹranko ń jẹ, (A mú wọn hù jáde). 32. (Wọ́n jẹ́ n̄ǹkan) ìgbádùn fún ẹ̀yin àti àwọn ẹran-ọ̀sìn yín.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute