Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
096

Al-'Alaq 96:16 ناصية كاذبة خاطية ١٦

96:16
نَاصِيَةٖ
كَٰذِبَةٍ
خَاطِئَةٖ
١٦
àásó orí òpùrọ́, ẹlẹ́ṣẹ̀.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Threat against Man's Transgression for the sake of Wealth

Allah informs that man is very pleased, most evil, scornful and transgressive when he considers himself self-sufficient and having an abundance of wealth. Then Allah threatens, warns and admonishes him in His saying,

إِنَّ إِلَى رَبِّكَ الر

…

The Threat against Man's Transgression for the sake of Wealth

Allah informs that man is very pleased, most evil, scornful and transgressive when he con

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 96, Page 598, Juz 30

6. Ní ti òdodo, dájúdájú ènìyàn kúkú ń tayọ ẹnu-ààlà 7. nítorí pé ó rí ara rẹ̀ ní ọlọ́rọ̀. 8. Dájúdájú ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ ni àbọ̀ ẹ̀dá. 9. Sọ fún mi nípa ẹni tó ń kọ̀ 10. fún ẹrúsìn kan nígbà tí (ẹrúsìn náà) kírun! 11. Sọ fún mi (nípa ẹ̀san rẹ̀) tí ó bá jẹ́ pé ó wà lórí ìmọ̀nà (’Islām) 12. tàbí pé ó pàṣẹ ìbẹ̀rù (Allāhu)! 13. Sọ fún mi (nípa ìyà rẹ̀) tí ó bá jẹ́ pé ó pe òdodo ní irọ́, tí ó sì kẹ̀yìn sí i? 14. Ṣé kò mọ̀ pé dájúdájú Allāhu ń rí (òun ni?) 15. Rárá (ọ̀rọ̀ kò rí bí ọ̀tá Allāhu ṣe rò ó sí.) Dájúdájú tí kò bá jáwọ́ (níbi dídí Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - lọ́wọ́), dájúdájú A máa fi àásó orí rẹ̀ wọ́ ọ (sínú Iná); 16. àásó orí òpùrọ́, ẹlẹ́ṣẹ̀. 17. Nítorí náà, kí ó pe àwọn olùbájókòó rẹ̀. 18. Àwa máa pe àwọn mọlāika ẹ̀ṣọ́ Iná. 19. Rárá (ọ̀rọ̀ kò rí bí ó ṣe ń sọ nípa Wa). Má ṣe tẹ̀lé tirẹ̀. Forí kanlẹ̀ (kí o kírun), kí o sì súnmọ́ (Allāhu).

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute