Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
090

Al-Balad 90:19 والذين كفروا باياتنا هم اصحاب المشامة ١٩

90:19
وَٱلَّذِينَ
كَفَرُواْ
بِـَٔايَٰتِنَا
هُمۡ
أَصۡحَٰبُ
ٱلۡمَشۡـَٔمَةِ
١٩
Àwọn tó sì ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Wa, àwọn ni èrò ọwọ́ òsì.1
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Encouragement to traverse upon the Path of Goodness

Ibn Zayd said,

فَلاَ اقتَحَمَ الْعَقَبَةَ

(But he has not attempted to pass on the path that is steep.) "This means, will he not traverse upon the path which contains salvation and good Then He explains this path by his saying,

وَمَآ أَدْرَاكَ مَا

…

The Encouragement to traverse upon the Path of Goodness

Ibn Zayd said,

فَلاَ اقتَحَمَ الْعَقَبَةَ

(But he has not attempted to pass on the path that is s

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 90, Page 595, Juz 30

11. Kò sì lọ rin ojú-ọ̀nà orí àpáta tó ṣòroó gùn fún ìgbàlà ẹ̀mí níbi Iná! 12. Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ ojú-ọ̀nà orí àpáta tó ṣòroó gùn fún ìgbàlà ẹ̀mí? 13. (Òhun ni) títú ẹrú sílẹ̀ lóko ẹrú. 14. Tàbí fífún ènìyàn ní oúnjẹ ní ọjọ́ ebi. 15. (Ẹ lè fún) ọmọ-òrukàn nínú ẹbí, 16. tàbí mẹ̀kúnnù tí kò ní gá tí kò ní go (olòṣì paraku). 17. Lẹ́yìn náà, kí ó wà nínú àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ń gbara wọn níyànjú sùúrù ṣíṣe, tí wọ́n sì tún ń gbara wọn níyànjú àánú ṣíṣe. 18. Àwọn wọ̀nyẹn ni èrò ọwọ́ ọ̀tún. 19. Àwọn tó sì ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Wa, àwọn ni èrò ọwọ́ òsì. 20. Wọ́n máa ti àwọn ìlẹ̀kùn Iná pa mọ́ wọn lórí pátápátá.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute