Al-Baqarah 2:129 ربنا وابعث فيهم رسولا منهم يتلو عليهم اياتك ويعلمهم الكتاب والحكمة ويزكيهم انك انت العزيز الحكيم ١٢٩
رَبَّنَا
وَٱبۡعَثۡ
فِيهِمۡ
رَسُولٗا
مِّنۡهُمۡ
يَتۡلُواْ
عَلَيۡهِمۡ
ءَايَٰتِكَ
وَيُعَلِّمُهُمُ
ٱلۡكِتَٰبَ
وَٱلۡحِكۡمَةَ
وَيُزَكِّيهِمۡۖ
إِنَّكَ
أَنتَ
ٱلۡعَزِيزُ
ٱلۡحَكِيمُ
١٢٩
Olúwa wa, gbé dìde nínú wọn Òjíṣẹ́ kan láààrin wọn, (ẹni tí) ó máa ké àwọn āyah Rẹ fún wọn, tí ó máa kọ́ wọn ní Tírà àti ọgbọ́n ìjìnlẹ̀ (sunnah), tí ó sì máa sọ wọ́n di ẹni mímọ́. Dájúdájú Ìwọ ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n.”
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Ibrahim's Supplication that Allah sends the Prophet
Allah mentioned Ibrahim's supplication for the benefit of the people of the Sacred Area (to grant them security and provision), and it was perfected by invoking Allah to send a Messenger from his offspring. This accepted supplication, from Ibrahim,
…Ibrahim's Supplication that Allah sends the Prophet
Allah mentioned Ibrahim's supplication for the benefit of the people of the Sacred Area (to grant t
…