Al-Baqarah 2:188 ولا تاكلوا اموالكم بينكم بالباطل وتدلوا بها الى الحكام لتاكلوا فريقا من اموال الناس بالاثم وانتم تعلمون ١٨٨
وَلَا
تَأۡكُلُوٓاْ
أَمۡوَٰلَكُم
بَيۡنَكُم
بِٱلۡبَٰطِلِ
وَتُدۡلُواْ
بِهَآ
إِلَى
ٱلۡحُكَّامِ
لِتَأۡكُلُواْ
فَرِيقٗا
مِّنۡ
أَمۡوَٰلِ
ٱلنَّاسِ
بِٱلۡإِثۡمِ
وَأَنتُمۡ
تَعۡلَمُونَ
١٨٨
Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ fi èrú jẹ dúkìá yín láààrin ara yín. Ẹ̀yin kò sì gbọdọ̀ gbé dúkìá lọ bá àwọn adájọ́ (ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀) nítorí kí ẹ lè fi ẹ̀ṣẹ̀ jẹ ìpín kan nínú dúkìá àwọn ènìyàn, ẹ̀yin sì mọ̀ (pé ìjà àbòsí lẹ̀ ń jà).
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Bribery is prohibited and is a Sin
`Ali bin Abu Talhah reported that Ibn `Abbas said, "This (Ayah 2:188) is about the indebted person when there is no evidence of the loan. So he denies taking the loan and the case goes to the authorities, even though he knows that it is not his money and that he is
…Bribery is prohibited and is a Sin
`Ali bin Abu Talhah reported that Ibn `Abbas said, "This (Ayah 2:188) is about the indebted person when there is no
…