Al-Baqarah 2:58 واذ قلنا ادخلوا هاذه القرية فكلوا منها حيث شيتم رغدا وادخلوا الباب سجدا وقولوا حطة نغفر لكم خطاياكم وسنزيد المحسنين ٥٨
وَإِذۡ
قُلۡنَا
ٱدۡخُلُواْ
هَٰذِهِ
ٱلۡقَرۡيَةَ
فَكُلُواْ
مِنۡهَا
حَيۡثُ
شِئۡتُمۡ
رَغَدٗا
وَٱدۡخُلُواْ
ٱلۡبَابَ
سُجَّدٗا
وَقُولُواْ
حِطَّةٞ
نَّغۡفِرۡ
لَكُمۡ
خَطَٰيَٰكُمۡۚ
وَسَنَزِيدُ
ٱلۡمُحۡسِنِينَ
٥٨
(Ẹ rántí) nígbà tí A sọ pé: “Ẹ wọ inú ìlú yìí.1 Ẹ jẹ nínú ìlú náà níbikíbi tí ẹ bá fẹ́ ní gbẹdẹmukẹ. Ẹ gba ẹnu-ọ̀nà (ìlú) náà wọlé ní ìtẹríba.2 Kí ẹ sì wí pé: “Ha ẹ̀ṣẹ̀ wa dànù.” A óò forí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jìn yín. A ó sì ṣe àlékún (ẹ̀san rere) fún àwọn olùṣe-rere.
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Jews were Rebellious instead of Appreciative when They gained Victory
Allah admonished the Jews for avoiding Jihad and not entering the holy land as they had been ordered to do when they came from Egypt with Musa. They were also commanded to fight the disbelieving `Amaliq (Canaanites) dwelling i
…The Jews were Rebellious instead of Appreciative when They gained Victory
Allah admonished the Jews for avoiding Jihad and not entering the holy land
…