Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
089

Al-Fajr 89:8 التي لم يخلق مثلها في البلاد ٨

89:8
ٱلَّتِي
لَمۡ
يُخۡلَقۡ
مِثۡلُهَا
فِي
ٱلۡبِلَٰدِ
٨
àwọn tí A kò dá irú wọn mọ́ sínú ìlú?
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

Recitation of Surat Al-Fajr in the Prayer

An-Nasa'i recorded a narration from Jabir that Mu`adh prayed a prayer and a man came and joined him in the prayer. Mu`adh made the prayer long, so the man went and prayed (alone) at the side of the Masjid, and then left. When Mu`ad

…

Which was revealed in Makkah

Recitation of Surat Al-Fajr in the Prayer

An-Nasa'i recorded a narration from Jabir that Mu`adh prayed a prayer and a man c

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 89, Page 593, Juz 30

1. Allāhu fi àfẹ̀mọ́júmọ́ búra. 2. Ó tún fi àwọn òru mẹ́wàá kan búra. 3. Ó tún fi n̄ǹkan tí eéjì ń pín geerege àti n̄ǹkan tí eéjì kò pín geerege búra. 4. Ó tún fi òru nígbà tí ó bá dé búra. 5. Ǹjẹ́ ìbúra wà nínú ìyẹn fún onílàákàyè? 6. Ṣé o kò wòye sí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ará ‘Ād, 7. (ìyẹn àwọn ìran) ’Irọm, àwọn òmìrán, 8. àwọn tí A kò dá irú wọn mọ́ sínú ìlú? 9. Àti àwọn Thamūd tí wọ́n gbẹ́ (ilé ìgbé) sínú àpáta nínú àfonúfojì, 10. àti Fir‘aon eléèkàn (ìyà)? 11. (Àwọn wọ̀nyí ni) àwọn tó tayọ ẹnu-ààlà nínú ìlú. 12. Wọ́n sì ṣe ìbàjẹ́ púpọ̀ sínú rẹ̀. 13. Olúwa rẹ sì rọ̀jò ìyà lé wọn lórí. 14. Dájúdájú Olúwa rẹ wà ní ibùṣọ́ (iṣẹ́ ẹ̀dá).

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute