Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
088

Al-Ghashiyah 88:2 وجوه يوميذ خاشعة ٢

88:2
وُجُوهٞ
يَوۡمَئِذٍ
خَٰشِعَةٌ
٢
Àwọn ojú kan yóò wálẹ̀ (ní ti ìyẹpẹrẹ) ní ọjọ́ yẹn.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

Reciting Surat Al-A`la and Al-Ghashiyah in the Friday Prayer

It has already been mentioned on the authority of An-Nu`man bin Bashir that the Messenger of Allah ﷺ used to recite Surat Al-A`la (87) and Al-Ghashiyah in the `Id and Friday prayers. Imam Malik recorded that Ad-D

…

Which was revealed in Makkah

Reciting Surat Al-A`la and Al-Ghashiyah in the Friday Prayer

It has already been mentioned on the authority of An-Nu`man bi

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 88, Page 592, Juz 30

1. Ṣebí ọ̀rọ̀ nípa ohun tó máa bo ẹ̀dá mọ́lẹ̀ ti dé ọ̀dọ̀ rẹ? 2. Àwọn ojú kan yóò wálẹ̀ (ní ti ìyẹpẹrẹ) ní ọjọ́ yẹn. 3. Wọ́n ṣe iṣẹ́ àṣekúdórógbó (ni nílé ayé). 4. Wọ́n sì máa wọ inú Iná tó gbóná janjan (ní ọ̀run). 5. Wọ́n sì máa fún (wọn) ní omi ìṣẹ́lẹ̀rú gbígbóná mu. 6. Kò sí oúnjẹ kan fún wọn àyàfi igi ẹlẹ́gùn-ún gbígbẹ. 7. Kò níí mú wọn sanra. Kò sì níí rọ̀ wọ́n lọ́rọ̀ nínú ebi. 8. Àwọn ojú kan yó sì kún fún ìgbádùn ní ọjọ́ yẹn 9. nítorí pé (ó) yọ́nú sí (ẹ̀san) iṣẹ́ rẹ̀. 10. (Ó máa) wà nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra gíga. 11. Wọn kò níí gbọ́ ìsọkúsọ nínú rẹ̀. 12. Omi ìṣẹ́lẹ̀rú tó ń ṣàn wà nínú rẹ̀. 13. Àwọn ibùsùn tí wọ́n gbé sókè wà nínú rẹ̀, 14. àti àwọn ife ìmumi tí wọ́n gbé kalẹ̀ (sí àrọ́wọ́tó wọn), 15. àti àwọn ìrọ̀rí tí wọ́n tò sí ẹ̀gbẹ́ ara wọn, 16. àti àwọn ìtẹ́ àtẹ́ẹ̀ká.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute