Al-Jinn 72:23 الا بلاغا من الله ورسالاته ومن يعص الله ورسوله فان له نار جهنم خالدين فيها ابدا ٢٣
إِلَّا
بَلَٰغٗا
مِّنَ
ٱللَّهِ
وَرِسَٰلَٰتِهِۦۚ
وَمَن
يَعۡصِ
ٱللَّهَ
وَرَسُولَهُۥ
فَإِنَّ
لَهُۥ
نَارَ
جَهَنَّمَ
خَٰلِدِينَ
فِيهَآ
أَبَدًا
٢٣
Àfi (kí n̄g ṣe) ìkédé ẹ̀sìn (tó wá) láti ọ̀dọ̀ Allāhu àti pé (kí n̄g sì jẹ́) àwọn iṣẹ́ Rẹ̀ (t’Ó fi rán mi). Ẹnikẹ́ni tó bá yapa Allāhu àti Òjíṣẹ́ Rẹ̀, dájúdájú iná Jahanamọ ń bẹ fún un. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀ títí láéláé.
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Command to worship Allah Alone and shun Shirk
Allah commands His servants to single Him out alone for worship and that none should be supplicated to along with Him, nor should any partners be associated with Him. As Qatadah said concerning Allah's statement,
وَأَنَّ الْمَسَـجِدَ لِلَّهِ فَلاَ تَدْ
…The Command to worship Allah Alone and shun Shirk
Allah commands His servants to single Him out alone for worship and that none should be supplicated t
…