Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
074

Al-Muddaththir 74:21 ثم نظر ٢١

74:21
ثُمَّ
نَظَرَ
٢١
Lẹ́yìn náà, ó wò sùn.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

A Threat for Whoever claims that the Qur'an is Magic

Allah threatens this wicked person whom He has favored with the blessings of this world, yet he is ungrateful for the blessings of Allah and he meets them with disbelief (in Allah) and rejection of His Ayat. He invents lies against Allah's Ayat and

…

A Threat for Whoever claims that the Qur'an is Magic

Allah threatens this wicked person whom He has favored with the blessings of this world, yet he is

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 74, Page 576, Juz 29

8. Nígbà tí wọ́n bá fọn fèrè oníwo fún àjíǹde, 9. ìyẹn, ní ọjọ́ yẹn, ni ọjọ́ ìnira, 10. tí kò níí rọrùn fún àwọn aláìgbàgbọ́. 11. Fi Mí dá ẹni tí Mo dá ní òun nìkan (ìyẹn nínú ikùn ìyá rẹ̀). 12. Mo sì fún un ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ dúkìá 13. àti àwọn ọmọkúnrin tó ń bẹ pẹ̀lú rẹ̀. 14. Mo sì fi àyè ìrọ̀rùn gbá a dáadáa. 15. Lẹ́yìn náà, ó tún ń jẹ̀rankàn pé kí N̄g ṣe àlékún. 16. Rárá o! Dájúdájú ó jẹ́ alátakò sí àwọn āyah Wa. 17. Èmi yóò la ìyà pọ́nkèpọ́nkè bọ̀ ọ́ lọ́rùn (nínú Iná). 18. Dájúdájú ó ronú (lódì nípa al-Ƙur’ān). Ó sì pinnu (ọ̀rọ̀ kan nínú ẹ̀mí rẹ̀). 19. Wọ́n sì ṣẹ́bi lé e nípa bí ó ṣe pinnu. 20. Lẹ́yìn náà, Wọ́n tún ṣẹ́bi lé e nípa bí ó ṣe pinnu. 21. Lẹ́yìn náà, ó wò sùn. 22. Lẹ́yìn náà, ó fajú ro, ó sì dijú mágbárí. 23. Lẹ́yìn náà, ó pẹ̀yìndà, ó sì ṣègbéraga. 24. Ó sì wí pé: “Kí ni èyí bí kò ṣe idán àtọwọ́dọ́wọ́. 25. Kí ni èyí bí kò ṣe ọ̀rọ̀ abara” 26. Èmi yóò fi sínú iná Saƙọr. 27. Kí l’ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ iná Saƙọr? 28. (Saƙọr) kò níí ṣẹ́ ẹ kù, kò sì níí pa á tì. 29. Ó máa jó awọ ara di dúdú. 30. (Àwọn mọlāika) mọ́kàndínlógún ni ẹ̀ṣọ́ rẹ̀. 31. Àwa kò ṣe ẹnì kan ní ẹ̀ṣọ́ Iná àfi àwọn mọlāika. Àwa kò sì ṣe òǹkà wọn (bẹ́ẹ̀) bí kò ṣe (nítorí kí ó lè jẹ́) àdánwò fún àwọn tó ṣàì gbàgbọ́, àti nítorí kí àwọn tí A fún ní Tírà lè ní àmọ̀dájú àti nítorí kí àwọn tí wọ́n gbàgbọ́ ní òdodo lè lékún ní ìgbàgbọ́ òdodo. (Ó rí bẹ́ẹ̀) nítorí kí àwọn tí A fún ní Tírà àti àwọn onígbàgbọ́ òdodo má baà ṣeyèméjì àti nítorí kí àwọn tí àrùn wà nínú ọkàn wọn àti àwọn aláìgbàgbọ́ lè wí pé: “Kí ni Allāhu gbà lérò pẹ̀lú àpèjúwe yìí?” Báyẹn ni Allāhu ṣe ń ṣi ẹni tí Ó bá fẹ́ lọ́nà, Ó sì ń tọ́ ẹni tí Ó bá fẹ́ sọ́nà. Kò sì sí ẹni tí ó mọ àwọn ọmọ ogun Olúwa rẹ àfi Òun náà. (Iná Saƙọr) kò sì jẹ́ kiní kan bí kò ṣe ìrántí fún abara.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute