Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
074

Al-Muddaththir 74:42 ما سلككم في سقر ٤٢

74:42
مَا
سَلَكَكُمۡ
فِي
سَقَرَ
٤٢
“Kí ni ó mu yín wọ inú iná Saƙọr?”
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

What will take place in the Discussion between the People of Paradise and the People of the Hellfire

Allah informs that,

كُلُّ نَفْسٍ بِمَا كَسَبَتْ رَهِينَةٌ

(Every person is a pledge for what he has earned,) meaning, bound to his deed on the Day of Judgement. Ibn `Abbas and others have said this.

…

What will take place in the Discussion between the People of Paradise and the People of the Hellfire

Allah informs that,

كُلُّ نَفْسٍ بِمَا كَسَبَتْ ر

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 74, Page 576, Juz 29

32. Ẹ gbọ́! Allāhu fi òṣùpá búra. 33. Ó tún fi alẹ́ nígbà tí ó bá lọ búra. 34. Ó tún fi òwúrọ̀ nígbà tí ojúmọ́ bá mọ́ búra. 35. Dájúdájú (iná Saƙọr) ni ọ̀kan nínú (àwọn àdánwò) tó tóbi. 36. (Ó jẹ́) ìkìlọ̀ fún abara. 37. Fún ẹni tí ó bá fẹ́ nínú yín láti tẹ̀ síwájú tàbí láti fà sẹ́yìn (nínú ẹ̀ṣẹ̀). 38. Ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan ni onídùúró fún ohun tó ṣe níṣẹ́. 39. Àyàfi àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún. 40. Wọn yóò máa bira wọn léèrè ọ̀rọ̀ nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra 41. nípa àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ pé: 42. “Kí ni ó mu yín wọ inú iná Saƙọr?” 43. Wọn yóò wí pé: “Àwa kò sí nínú àwọn olùkírun ni. 44. Àwa kò sì sí nínú àwọn tó ń bọ́ àwọn mẹ̀kúnnù. 45. Àwa sì máa ń sọ ìsọkúsọ pẹ̀lú àwọn onísọkúsọ. 46. Àti pé àwa máa ń pe Ọjọ́ ẹ̀san ní irọ́ 47. títí ikú fi dé bá wa.” 48. Ìpẹ̀ àwọn olùṣìpẹ̀ kò sì níí ṣe wọ́n ní àǹfààní.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute