Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
023

Al-Mu'minun 23:4 والذين هم للزكاة فاعلون ٤

23:4
وَٱلَّذِينَ
هُمۡ
لِلزَّكَوٰةِ
فَٰعِلُونَ
٤
àti àwọn tó ń ṣe àfọ̀mọ́ (ẹ̀mí àti ara) wọn.1
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was Revealed in Makkah

بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ

In the Name of Allah, the Most Gracious, the Most Merciful.

The Success is for the believers whose qualities are described here

قَدْ أَفْلَحَ الْمُؤْمِنُونَ

(Successful indeed are the believers) means, they have attained victory and are

…

Which was Revealed in Makkah

بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ

In the Name of Allah, the Most Gracious, the Most Merciful.

The Success is for the be

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 23, Page 342, Juz 18

1. Dájúdájú àwọn onígbàgbọ́ òdodo ti jèrè. 2. Àwọn tó ń páyà (Allāhu) nínú ìrun wọn, 3. àti àwọn tó ń ṣẹ́rí kúrò níbi ìsọkúsọ, 4. àti àwọn tó ń ṣe àfọ̀mọ́ (ẹ̀mí àti ara) wọn. 5. àti àwọn tó ń ṣọ́ abẹ́ wọn, 6. àfi ní ọ̀dọ̀ àwọn ìyàwó wọn àti ẹrúbìnrin wọn. Dájúdájú wọn kì í ṣe ẹni èébú (tí wọ́n bá súnmọ́ wọn), 7. nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá wá òmíràn (súnmọ́) lẹ́yìn ìyẹn, àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn olùtayọ ẹnu-ààlà, 8. àti àwọn tó ń ṣọ́ àgbàfipamọ́ wọn àti àdéhùn wọn, 9. àti àwọn tó ń ṣọ́ ìrun wọn; 10. àwọn wọ̀nyẹn ni àwọn olùjogún, 11. àwọn tó máa jogún ọgbà ìdẹ̀ra Firdaos. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute