Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
077

Al-Mursalat 77:35 هاذا يوم لا ينطقون ٣٥

77:35
هَٰذَا
يَوۡمُ
لَا
يَنطِقُونَ
٣٥
Èyí ni ọjọ́ tí wọn kò níí sọ̀rọ̀.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The driving of the Criminals to their Final Abode in Hell and how it will be done

Allah informs about the disbelievers who deny the final abode, the recompense, Paradise, and the Hellfire. On the Day of Judgement it will be said to them:

انطَلِقُواْ إِلَى مَا كُنتُمْ بِهِ تُكَذِّبُونَ - انطَلِقُواْ إِ
…

The driving of the Criminals to their Final Abode in Hell and how it will be done

Allah informs about the disbelievers who deny the final abode, the re

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 77, Page 581, Juz 29

25. Ǹjẹ́ Àwa kò ṣe ilẹ̀ ní ohun tó ń kó ẹ̀dá jọ mọ́ra wọn; 26. (ìyẹn) àwọn alààyè àti àwọn òkú? 27. A sì fi àwọn àpáta gbagidi gíga-gíga sínú rẹ̀. A sì fún yín ní omi dídùn mu. 28. Ègbé ni ní ọjọ́ yẹn fún àwọn olùpe-òdodo-nírọ́. 29. Ẹ máa lọ sí ibi tí ẹ̀ ń pè ní irọ́. 30. Ẹ máa lọ sí ibi èéfín ẹlẹ́ka mẹ́ta. 31. Kì í ṣe ibòji tútù. Kò sì níí rọ̀ wọ́n lọ́rọ̀ nínú ìjòfòfò Iná. 32. Dájúdájú (Iná náà) yóò máa ju ẹ̀tapàrà (rẹ̀ sókè tó máa dà) bí pẹ̀tẹ́ẹ̀sì. 33. (Ó máa dà) bí àwọn ràkúnmí aláwọ̀ omi ọsàn. 34. Ègbé ni ní ọjọ́ yẹn fún àwọn olùpe-òdodo-nírọ́ 35. Èyí ni ọjọ́ tí wọn kò níí sọ̀rọ̀. 36. A kò sì níí yọ̀ǹda (ọ̀rọ̀ sísọ) fún wọn, áḿbọ̀sìbọ́sí pé wọ́n yóò mú àwáwí wá. 37. Ègbé ni ní ọjọ́ yẹn fún àwọn olùpe-òdodo-nírọ́. 38. Èyí ni ọjọ́ ìpínyà. Àwa yó sì kó ẹ̀yin àti àwọn ẹni àkọ́kọ́ jọ. 39. Tí ẹ bá ní ète kan lọ́wọ́, ẹ déte sí Mi wò. 40. Ègbé ni ní ọjọ́ yẹn fún àwọn olùpe-òdodo-nírọ́.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute