Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
056

Al-Waqi'ah 56:3 خافضة رافعة ٣

56:3
خَافِضَةٞ
رَّافِعَةٌ
٣
ó máa mú (àwọn kan) wálẹ̀ (sínú Iná), ó sì máa gbé (àwọn kan) sókè (nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra).
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

The Virtues of Surat Al-Waqi`ah

Abu Ishaq reported from `Ikrimah from Ibn `Abbas that Abu Bakr said, "O Allah's Messenger! You are becoming gray" The Messenger ﷺ replied,

«شَيَّبَتْنِي هُودٌ وَالْوَاقِعَةُ وَالْمُرْسَلَاتُ وَعَمَّ يَتَسَاءَلُونَ وَإِذَا الشَّمْسُ كُوِّرَت»

(

…

Which was revealed in Makkah

The Virtues of Surat Al-Waqi`ah

Abu Ishaq reported from `Ikrimah from Ibn `Abbas that Abu Bakr said, "O Allah's Messenger!

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 56, Page 534, Juz 27

1. Nígbà tí Ìṣẹ̀lẹ̀ (Àjíǹde) bá ṣẹlẹ̀, 2. - kò sí irọ́ kan nípa ìṣẹ̀lẹ̀ rẹ̀- 3. ó máa mú (àwọn kan) wálẹ̀ (sínú Iná), ó sì máa gbé (àwọn kan) sókè (nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra). 4. Nígbà tí wọ́n bá mi ilẹ̀ tìtì ní mímìtìtì, 5. àti nígbà tí Wọ́n bá fọ́ àwọn àpáta ní fífọ́ wómúwómú, 6. - wọ́n sì máa di eruku àfẹ́dànù - 7. ẹ̀yin sì máa jẹ́ oríṣi mẹ́ta. 8. Àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún, kí ni (ó máa ti dára tó fún) àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún? 9. Àwọn èrò ọwọ́ òsì, kí ni (ó máa ti burú tó fún) àwọn èrò ọwọ́ òsì? 10. Àwọn aṣíwájú sì ni àwọn aṣíwájú. 11. Àwọn wọ̀nyẹn ni alásùn-únmọ́ (Allāhu) 12. nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra. 13. Wọ́n pọ̀ nínú àwọn ẹni àkọ́kọ́. 14. Wọ́n sì kéré nínú àwọn ẹni Ìkẹ́yìn. 15. (Wọn yóò wà) lórí ìtẹ́ tí wọ́n fi góòlù hun. 16. Wọn yóò rọ̀gbọ̀kú sórí rẹ̀, wọn sì máa dojú kọra wọn. 17. Àwọn ọ̀dọ́kùnrin tí kò níí darúgbó yó sì máa lọ bọ̀ láààrin wọn 18. pẹ̀lú àwọn ife omi, ohun ìrọmi fẹ̀ǹfẹ̀ àti ife ọtí aládùn láti inú odò kan tó ń ṣàn (káà kiri ọ̀dọ̀ wọn). 19. Kò níí fọ́ wọn lórí; kò sì níí mú wọn húnrìrà. 20. Èso tí wọn yóò máa ṣẹ̀ṣà nínú rẹ̀ (tún wà fún wọn). 21. Àti ẹran ẹyẹ, èyí tí wọ́n ń fẹ́ (yó wà fún wọn). 22. Àwọn obìnrin ẹlẹ́yinjú ẹgẹ́ (tún wà fún wọn). 23. Wọ́n dà bí àlúùúlù (òkúta olówó-iye-bíye) tí wọ́n fi pamọ́ sínú apó rẹ̀. 24. (Ìwọ̀nyí ni) ẹ̀san fún ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́. 25. Wọn kò níí gbọ́ ìsọkúsọ àti ọ̀rọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ nínú Ọgbà Ìdẹ̀ra. 26. Àyàfi ọ̀rọ̀ àlàáfíà, àlàáfíà.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute