Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
056

Al-Waqi'ah 56:90 واما ان كان من اصحاب اليمين ٩٠

56:90
وَأَمَّآ
إِن
كَانَ
مِنۡ
أَصۡحَٰبِ
ٱلۡيَمِينِ
٩٠
Ní ti ẹni tí ó bá wà nínú àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún,
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Condition of People at the Time of Their Death

These are the three types of conditions that people face upon their death. Either they are among the near believers or those below their rank on the right, or those who denied the truth, were led astray from the guidance and were ignorant about Allah

…

The Condition of People at the Time of Their Death

These are the three types of conditions that people face upon their death. Either they are among the

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 56, Page 537, Juz 27

75. Nítorí náà, Mò ń fi àwọn àyè tí ìkọ̀ọ̀kan gbólóhùn al-Ƙur’ān wà nínú sánmọ̀ búra. 76. Dájúdájú ìbúra ńlá ni, tí ẹ bá mọ̀. 77. Dájúdájú (al-Ƙur’ān) ni n̄ǹkan kíké alápọ̀n-ọ́nlé. 78. Ó wà nínú Tírà kan tí wọ́n ń fi ààbò bò (ìyẹn Laohul-Mahfūṭḥ). 79. Kò sí ẹni tó lè fọwọ́ kàn án (ní ọ̀dọ̀ Allāhu) àfi àwọn ẹni mímọ́ (ìyẹn, àwọn mọlāika). 80. Wọ́n sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Olúwa gbogbo ẹ̀dá. 81. Nítorí náà, ṣé ọ̀rọ̀ (al-Ƙur’ān) yìí l’ẹ̀ ń pè ní irọ́? 82. Ẹ sì ń sọ ìdúpẹ́ arísìkí yín di pé dájúdájú ẹ̀ ń pe òdodo ní irọ́. 83. Kí ni ó máa ti rí (fún yín) nígbà tí ẹ̀mí (yín) bá dé ọ̀nà ọ̀fun, 84. tí ẹ̀yin yó sì máa wò bọ̀ọ̀ nígbà yẹn? 85. Àwa sì súnmọ́ ọn ju ẹ̀yin lọ, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò ríran. 86. Ẹ̀yin kò ṣe jẹ́ ẹni tí A ò níí gbẹ̀san lára rẹ̀, 87. kí ẹ sì dá (ẹ̀mí tí ó fẹ́ bọ́) padà, tí ẹ bá jẹ́ olódodo. 88. Ní ti ẹni tí ó bá wà nínú àwọn alásùn-únmọ́ (Wa), 89. ìsinmi, èsè tó dára àti Ọgbà Ìdẹ̀ra (ni tirẹ̀). 90. Ní ti ẹni tí ó bá wà nínú àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún, 91. àlàáfíà ni fún ọ láààrin àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún. 92. Ní ti ẹni tí ó bá wà nínú àwọn olùpe-òdodo-nírọ́, àwọn olùṣìnà, 93. n̄ǹkan àlejò (wọn) ni omi tó gbóná parí 94. àti wíwọ inú iná Jẹhīm. 95. Dájúdájú èyí, òhun ni òdodo tó dájú. 96. Nítorí náà, ṣàfọ̀mọ́ fún orúkọ Olúwa rẹ, Atóbi.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute