Ali 'Imran 3:146 وكاين من نبي قاتل معه ربيون كثير فما وهنوا لما اصابهم في سبيل الله وما ضعفوا وما استكانوا والله يحب الصابرين ١٤٦
وَكَأَيِّن
مِّن
نَّبِيّٖ
قَٰتَلَ
مَعَهُۥ
رِبِّيُّونَ
كَثِيرٞ
فَمَا
وَهَنُواْ
لِمَآ
أَصَابَهُمۡ
فِي
سَبِيلِ
ٱللَّهِ
وَمَا
ضَعُفُواْ
وَمَا
ٱسۡتَكَانُواْۗ
وَٱللَّهُ
يُحِبُّ
ٱلصَّٰبِرِينَ
١٤٦
Mélòó mélòó nínú àwọn Ànábì tí wọ́n ti jagun ẹ̀sìn pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹgbẹẹgbẹ̀rún (ọmọ-ẹ̀yìn wọn). Wọn kò ní ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn nípa ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wọn ní ojú-ọ̀nà Allāhu. Wọn kò kọ́lẹ, wọn kò sì jura wọn sílẹ̀ fún ọ̀tá ẹ̀sìn. Allāhu sì nífẹ̀ẹ́ àwọn onísùúrù.
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Rumor that the Prophet was Killed at Uhud
When Muslims suffered defeat in battle at Uhud and some of them were killed, Shaytan shouted, "Muhammad ﷺ has been killed." Ibn Qami'ah went back to the idolators and claimed, "I have killed Muhammad." Some Muslims believed this rumor and thought that the
…The Rumor that the Prophet was Killed at Uhud
When Muslims suffered defeat in battle at Uhud and some of them were killed, Shaytan shouted, "Muhammad ﷺ
…