Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
078

An-Naba 78:22 للطاغين مابا ٢٢

78:22
لِّلطَّٰغِينَ
مَـَٔابٗا
٢٢
(Ó jẹ́) ibùgbé fún àwọn alákọyọ.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Explaining the Day of Decision and what occurs during it

Allah says about the Day of Decision -- and it is the Day of Judgement -- that it is at a fixed time, with a set appointment. Its time cannot be added to or decreased. No one knows its exact time except Allah. This is as Allah says,

وَمَا نُؤَخّ

…

Explaining the Day of Decision and what occurs during it

Allah says about the Day of Decision -- and it is the Day of Judgement -- that it is at a fixe

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 78, Page 582, Juz 30

17. Dájúdájú ọjọ́ ìpínyà, ó ní gbèdéke àkókò kan. 18. (Ìyẹn ni) ọjọ́ tí wọ́n á fọn fèrè oníwo fún àjíǹde. Ẹ̀yin yó sì máa wá níjọ-níjọ. 19. Wọ́n sì máa ṣí sánmọ̀ sílẹ̀. Ó sì máa di àwọn ìlẹ̀kùn. 20. Wọ́n máa mú àwọn àpáta rìn (bọ́ sí àyè mìíràn). Ó sì máa di ahúnpeéná. 21. Dájúdájú iná Jahanamọ, ó lúgọ sílẹ̀ lójú ọ̀nà. 22. (Ó jẹ́) ibùgbé fún àwọn alákọyọ. 23. Wọn yóò máa gbé inú rẹ̀ fún ìgbà gbọọrọ. 24. Wọn kò níí rí ìtura tàbí ohun mímu kan tọ́wò nínú rẹ̀, 25. àyàfi omi tó gbóná parí àti àwọnúwẹ̀jẹ̀. 26. (Ó jẹ́) ẹ̀san tó ṣe wẹ́kú (iṣẹ́ wọn). 27. Dájúdájú wọn kì í retí ìṣírò-iṣẹ́. 28. Wọ́n sì pe àwọn āyah Wa ní irọ́ gan-an. 29. Gbogbo n̄ǹkan sì ni A ti ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀ sínú Tírà kan. 30. Nítorí náà, ẹ tọ́ (ìyà) wò. A ò sì níí ṣe àlékún kan fún yín bí kò ṣe ìyà.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute