Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
053

An-Najm 53:22 تلك اذا قسمة ضيزى ٢٢

53:22
تِلۡكَ
إِذٗا
قِسۡمَةٞ
ضِيزَىٰٓ
٢٢
Ìpín àbòsí nìyẹn nígbà náà.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Refuting Idolatry, Al-Lat and Al-`Uzza

Allah the Exalted rebukes the idolators for worshipping idols and taking rivals to Him. They built houses for their idols to resemble the Ka`bah built by Prophet Ibrahim, Allah's Khalil.

أَفَرَءَيْتُمُ اللَّـتَ

(Have you then considered Al-Lat,) Al-Lat was a white

…

Refuting Idolatry, Al-Lat and Al-`Uzza

Allah the Exalted rebukes the idolators for worshipping idols and taking rivals to Him. They built houses for th

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 53, Page 526, Juz 27

19. Ẹ sọ fún mi nípa òrìṣà Lāt àti òrìṣà ‘Uzzā, 20. àti Mọnāh, òrìṣà kẹta mìíràn. 21. Ṣé ọmọkùnrin ni tiyín, ọmọbìnrin sì ni tiRẹ̀? 22. Ìpín àbòsí nìyẹn nígbà náà. 23. (Àwọn orúkọ òrìṣà wọ̀nyẹn) kò sì jẹ́ kiní kan bí kò ṣe àwọn orúkọ kan tí ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín sọ (àwọn òrìṣà yín fúnra yín). Allāhu kò sọ ẹ̀rí ọ̀rọ̀ kan kalẹ̀ nípa rẹ̀. Wọn kò sì tẹ̀lé kiní kan bí kò ṣe àbá dídá àti ohun tí ẹ̀mí (wọn) ń fẹ́ (ìfẹ́-inú). Ìmọ̀nà kúkú ti dé bá wọn láti ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. 24. Tàbí ti ènìyàn ni n̄ǹkan tó bá ń fẹ́! 25. Ti Allāhu sì ni ọ̀run àti ayé. 26. Àti pé mélòó mélòó nínú àwọn mọlāika tó wà nínú àwọn sánmọ̀, tí ìṣìpẹ̀ wọn kò níí rọ̀ wọ́n lọ́rọ̀ kiní kan àyàfi lẹ́yìn ìgbà tí Allāhu bá yọ̀ǹda fún ẹni tí Ó bá fẹ́, tí Ó sì yọ́nú sí. 27. Dájúdájú àwọn tí kò ní ìgbàgbọ́ òdodo nínú Ọjọ́ Ìkẹ́yìn, àwọn ni wọ́n ń fún àwọn mọlāika ní orúkọ obìnrin. 28. Kò sí ìmọ̀ kan fún wọn nípa rẹ̀. Wọn kò sì tẹ̀lé kiní kan bí kò ṣe àbá dídá. Dájúdájú àbá dídá kò sì níí rọrọ̀ kiní kan lára òdodo.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute