An-Naml 27:37 ارجع اليهم فلناتينهم بجنود لا قبل لهم بها ولنخرجنهم منها اذلة وهم صاغرون ٣٧
ٱرۡجِعۡ
إِلَيۡهِمۡ
فَلَنَأۡتِيَنَّهُم
بِجُنُودٖ
لَّا
قِبَلَ
لَهُم
بِهَا
وَلَنُخۡرِجَنَّهُم
مِّنۡهَآ
أَذِلَّةٗ
وَهُمۡ
صَٰغِرُونَ
٣٧
Padà sí ọ̀dọ̀ wọn. Dájúdájú à ń bọ̀ wá bá wọn pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun tí wọn kò lè kojú rẹ̀. Dájúdájú a máa mú wọn jáde kúrò nínú (ìlú wọn) ní ẹni yẹpẹrẹ, tí wọn yó sì di ẹni àbùkù.”
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Gift and the Response of Sulayman
More than one of the scholars of Tafsir among the Salaf and others stated that she sent him a huge gift of gold, jewels, pearls and other things. It is apparent that Sulayman, peace be upon him, did not even look at what they brought at all and did not pay any at
…The Gift and the Response of Sulayman
More than one of the scholars of Tafsir among the Salaf and others stated that she sent him a huge gift of gold,
…