Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
079

An-Nazi'at 79:13 فانما هي زجرة واحدة ١٣

79:13
فَإِنَّمَا
هِيَ
زَجۡرَةٞ
وَٰحِدَةٞ
١٣
Nítorí náà, igbe ẹyọ kan sì ni.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Tafsir of Surat An-Nazi`at (Chapter - 79) Which was revealed in Makkah

بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ

In the Name of Allah, the Most Gracious, the Most Merciful.

Swearing by Five Characteristics that the Day of Judgement will occur

Ibn Mas`ud, Ibn `Abbas, Masruq, Sa`id bin Jubayr, Abu Sa

…

The Tafsir of Surat An-Nazi`at (Chapter - 79) Which was revealed in Makkah

بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ

In the Name of Allah, the Most Graci

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 79, Page 583, Juz 30

1. Allāhu fi àwọn mọlāika tó ń fi ọ̀nà èle gba ẹ̀mí àwọn aláìgbàgbọ́ búra. 2. Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń fi ọ̀nà ẹ̀rọ̀ gba ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo búra. 3. Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń yára gágá níbi àṣẹ Rẹ̀ búra. 4. Ó tún fi àwọn mọlāika tó máa ṣíwájú ẹ̀mí àwọn onígbàgbọ́ òdodo wọnú Ọgbà Ìdẹ̀ra tààrà búra. 5. Ó tún fi àwọn mọlāika tó ń ṣètò nínú sánmọ̀ àti ilé ayé pẹ̀lú àṣẹ Allāhu búra. 6. Ní ọjọ́ tí ìmìtìtì máa mi gbogbo ayé tìtì. 7. Ohun tí ó máa tẹ̀lé e máa ṣẹlẹ̀ tẹ̀lé e. 8. Àwọn ọkàn yóò máa gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ ní ọjọ́ yẹn. 9. Ojú wọn yó sì wálẹ̀ ní ti ìyẹpẹrẹ. 10. Wọn yóò wí pé: “Ṣé Wọ́n tún máa dá wa padà sí ìbẹ̀rẹ̀ ìṣẹ̀mí (bíi tayé ni)? 11. Ṣé nígbà tí a ti di eegun tó kẹfun tán?” 12. Wọ́n wí pé: “Ìdápadà òfò nìyẹn nígbà náà (fún ẹni tó pè é ní irọ́.)” 13. Nítorí náà, igbe ẹyọ kan sì ni. 14. Nígbà náà ni wọn yóò bára wọn lórí ilẹ̀ gban̄sasa.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute