Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
079

An-Nazi'at 79:43 فيم انت من ذكراها ٤٣

79:43
فِيمَ
أَنتَ
مِن
ذِكۡرَىٰهَآ
٤٣
Níbo ni ìwọ wà sí ìmọ̀ rẹ̀ ná?1
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Day of Judgement, its Pleasures and Hell, and that its Time is not known

Allah says,

فَإِذَا جَآءَتِ الطَّآمَّةُ الْكُبْرَى

(But when there comes the Great Catastrophe) This refers to the Day of Judgement. This has been said by Ibn `Abbas. It has been called this because it will overcome every matt

…

The Day of Judgement, its Pleasures and Hell, and that its Time is not known

Allah says,

فَإِذَا جَآءَتِ الطَّآمَّةُ الْكُبْرَى

(But when there comes the

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 79, Page 584, Juz 30

34. Ṣùgbọ́n nígbà tí ìparun ńlá bá dé, 35. ní ọjọ́ tí ènìyàn yóò rántí ohun tó ṣe níṣẹ́. 36. Wọ́n sì máa fi Iná hàn kedere fún (gbogbo) ẹni tó ríran. 37. Nítorí náà, ní ti ẹni tó tayọ ẹnu-ààlà, 38. tí ó tún gbé àjùlọ fún ìṣẹ̀mí ayé, 39. dájúdájú iná Jẹhīm, òhun ni ibùgbé (rẹ̀). 40. Ní ti ẹni tí ó páyà ìdúró níwájú Olúwa rẹ̀, tí ó tún kọ ìfẹ́-inú fún ẹ̀mí (ara rẹ̀), 41. dájúdájú Ọgbà Ìdẹ̀ra, òhun ni ibùgbé (rẹ̀). 42. Wọ́n ń bi ọ́ léèrè nípa Àkókò náà pé: “Ìgbà wo l’ó máa ṣẹlẹ̀?” 43. Níbo ni ìwọ wà sí ìmọ̀ rẹ̀ ná? 44. Ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ ni òpin ìmọ̀ nípa rẹ̀ wà. 45. Ìwọ kúkú ni olùkìlọ̀ fún ẹni tó ń páyà rẹ̀. 46. Ní ọjọ́ tí wọ́n máa rí i, wọn máa dà bí ẹni pé wọn kò gbé ilé ayé tayọ ìrọ̀lẹ́ tàbí ìyálẹ̀ta (ọjọ́) kan.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute