An-Nur 24:38 ليجزيهم الله احسن ما عملوا ويزيدهم من فضله والله يرزق من يشاء بغير حساب ٣٨
لِيَجۡزِيَهُمُ
ٱللَّهُ
أَحۡسَنَ
مَا
عَمِلُواْ
وَيَزِيدَهُم
مِّن
فَضۡلِهِۦۗ
وَٱللَّهُ
يَرۡزُقُ
مَن
يَشَآءُ
بِغَيۡرِ
حِسَابٖ
٣٨
(Wọ́n ṣe rere wọ̀nyí) nítorí kí Allāhu lè san wọ́n ní ẹ̀san rere tó dára ju ohun tí wọ́n ṣe níṣẹ́ àti nítorí kí Ó lè ṣe àlékún fún wọn nínú oore àjùlọ Rẹ̀. Àti pé Allāhu ń pèsè ìjẹ-ìmu àti ìgbádùn fún ẹni tí Ó bá fẹ́ láì níí ní ìṣírò.1
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Virtues of the Masjids, the Correct Etiquette, and the Virtues of Those who take care of them
Having likened the heart of the believer and what it contains of guidance and knowledge to a lamp lit with good oil shining in a clear glass, Allah then states where it belongs, which is in the Masjids,
…The Virtues of the Masjids, the Correct Etiquette, and the Virtues of Those who take care of them
Having likened the heart of the believer and what it
…