Ar-Rum 30:55 ويوم تقوم الساعة يقسم المجرمون ما لبثوا غير ساعة كذالك كانوا يوفكون ٥٥
وَيَوۡمَ
تَقُومُ
ٱلسَّاعَةُ
يُقۡسِمُ
ٱلۡمُجۡرِمُونَ
مَا
لَبِثُواْ
غَيۡرَ
سَاعَةٖۚ
كَذَٰلِكَ
كَانُواْ
يُؤۡفَكُونَ
٥٥
Àti pé ní ọjọ́ tí Àkókò náà bá ṣẹlẹ̀ (ìyẹn, ọjọ́ Àjíǹde), àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ yóò máa búra pé àwọn kò gbé (ilé ayé) ju àkókò kan lọ.” Báyẹn ni wọ́n ṣe máa ń ṣẹ́rí wọn kúrò níbi òdodo.
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Ignorance of the Disbelievers in this World and in the Hereafter
Here Allah tells us of the ignorance of the disbelievers in this world and in the Hereafter. In this world they worship idols, and in the Hereafter they will also display great ignorance. They will swear by Allah that they did not e
…The Ignorance of the Disbelievers in this World and in the Hereafter
Here Allah tells us of the ignorance of the disbelievers in this world and in the
…