Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
037

As-Saffat 37:130 سلام على ال ياسين ١٣٠

37:130
سَلَٰمٌ
عَلَىٰٓ
إِلۡ يَاسِينَ
١٣٠
Àlàáfíà kí ó máa bá (Ànábì) ’Ilyās.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

إِذْ قَالَ لِقَوْمِهِ أَلاَ تَتَّقُونَ

(When he said to his people: "Will you not have Taqwa") means, `do you not fear Allah when you worship others instead of Him'

أَتَدْعُونَ بَعْلاً وَتَذَرُونَ أَحْسَنَ الْخَـلِقِينَ

(Will you call upon Ba`l and forsake the Best of creators,) Ibn `Abbas, may Allah

…
إِذْ قَالَ لِقَوْمِهِ أَلاَ تَتَّقُونَ

(When he said to his people: "Will you not have Taqwa") means, `do you not fear Allah when you worship others i

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 37, Page 451, Juz 23

123. Dájúdájú (Ànábì) ’Ilyās wà nínú àwọn Òjíṣẹ́. 124. (Ẹ rántí) nígbà tí ó sọ fún ìjọ rẹ̀ pé: “Ṣé ẹ ò níí bẹ̀rù Allāhu ni? 125. Ṣé ẹ óò máa pe òrìṣà kan, ẹ sì máa fi Ẹni tó dára jùlọ nínú àwọn ẹlẹ́dàá sílẹ̀? 126. (ẹ̀ ń fi) Allāhu (sílẹ̀), Olúwa yín àti Olúwa àwọn bàbá yín, àwọn ẹni àkọ́kọ́?” 127. Wọ́n sì pè é ní òpùrọ́. Nítorí náà, wọ́n máa mú wọn wá sínú Iná. 128. Àfi àwọn ẹrúsìn Allāhu, àwọn tí A ṣà lẹ́ṣà (fún ìgbàgbọ́ òdodo). 129. A fún un ní orúkọ rere láààrin àwọn ẹni ìkẹ́yìn. 130. Àlàáfíà kí ó máa bá (Ànábì) ’Ilyās. 131. Dájúdájú báyẹn ni Àwa ṣe ń san àwọn olùṣe-rere ní ẹ̀san (rere). 132. Dájúdájú ó wà nínú àwọn ẹrúsìn Wa, àwọn onígbàgbọ́ òdodo.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute