Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
037

As-Saffat 37:139 وان يونس لمن المرسلين ١٣٩

37:139
وَإِنَّ
يُونُسَ
لَمِنَ
ٱلۡمُرۡسَلِينَ
١٣٩
Dájúdájú (Ànábì) Yūnus kúkú wà nínú àwọn Òjíṣẹ́.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Story of Yunus

We have already discussed the story of Yunus, peace be upon him, in Surat Al-Anbiya' (21:87-88). In the Two Sahihs it is reported that the Messenger of Allah ﷺ said:

«مَا يَنْبَغِي لِعَبْدٍ أَنْ يَقُولَ: أَنَا خَيْرٌ مِنْ يُونُسَ بْنِ مَتَّى»

(It is not right for any person to say

…

The Story of Yunus

We have already discussed the story of Yunus, peace be upon him, in Surat Al-Anbiya' (21:87-88). In the Two Sahihs it is reported t

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 37, Page 451, Juz 23

139. Dájúdájú (Ànábì) Yūnus kúkú wà nínú àwọn Òjíṣẹ́. 140. (Ẹ rántí) nígbà tí ó sá lọ sínú ọkọ̀ ojú-omi tó kún (fún èrò). 141. Ó sì bá wọn ṣe kúríà papọ̀. Ó sì wà nínú àwọn tí kúrìá já. 142. Nítorí náà, ẹja gbé e mì; ó sì ń dá ara rẹ̀ lẹ́bi. 143. Nítorí náà, tí kò bá jẹ́ pé ó wà nínú àwọn olùṣàfọ̀mọ́ fún Allāhu, 144. dájúdájú ìbá wà nínú ẹja títí di ọjọ́ tí wọn yóò gbé ẹ̀dá dìde. 145. Nítorí náà, A jù ú sí orí ilẹ́ gban̄sasa létí omi. Ó sì jẹ́ aláìlera. 146. A sì mú igi Yẹƙtīn hù jáde láti ṣíji bò ó. 147. A tún rán an níṣẹ́ sí ọ̀kẹ́ márùn-ún (ènìyàn) tàbí kí wọ́n lékún sí i. 148. Wọ́n gbàgbọ́ ní òdodo. A sì fún wọn ní ìgbádùn títí di ìgbà díẹ̀.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute