Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
037

As-Saffat 37:168 لو ان عندنا ذكرا من الاولين ١٦٨

37:168
لَوۡ
أَنَّ
عِندَنَا
ذِكۡرٗا
مِّنَ
ٱلۡأَوَّلِينَ
١٦٨
“Tí ó bá jẹ́ pé dájúdájú a bá ní (tírà) ìrántí kan nínú (àwọn tírà) àwọn ẹni àkọ́kọ́,
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

No One believes what the Idolators say except Those Who are even more misguided than They

Allah says, addressing the idolators:

فَإِنَّكُمْ وَمَا تَعْبُدُونَ - مَآ أَنتُمْ عَلَيْهِ بِفَـتِنِينَ - إِلاَّ مَنْ هُوَ صَالِ الْجَحِيمِ

(So, verily you and those whom you worship cannot lead astray, except tho

…

No One believes what the Idolators say except Those Who are even more misguided than They

Allah says, addressing the idolators:

فَإِنَّكُمْ وَمَا تَعْبُ

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 37, Page 452, Juz 23

167. Wọ́n kúkú ń wí pé: 168. “Tí ó bá jẹ́ pé dájúdájú a bá ní (tírà) ìrántí kan nínú (àwọn tírà) àwọn ẹni àkọ́kọ́, 169. dájúdájú àwa ìbá jẹ́ ẹrúsìn Allāhu, àwọn tí A ṣà lẹ́ṣà (fún ìgbàgbọ́ òdodo).” 170. Ṣùgbọ́n wọ́n ṣàì gbàgbọ́ nínú (Allāhu). Láìpẹ́ wọ́n máa mọ̀. 171. Dájúdájú ọ̀rọ̀ Wa ti ṣíwájú fún àwọn ẹrúsìn Wa, àwọn Òjíṣẹ́. 172. Dájúdájú àwọn, àwọn l’a kúkú máa ṣàrànṣe fún. 173. Àti pé dájúdájú àwọn ọmọ ogun Wa, àwọn kúkú ni olùborí. 174. Nítorí náà, ṣẹ́rí kúrò lọ́dọ̀ wọn fún ìgbà díẹ̀. 175. Àti pé máa wò wọ́n níran ná, àwọn náà ń bọ̀ wá ríran wò. 176. Ṣé ìyà Wa ni wọ́n ń wá pẹ̀lú ìkánjú? 177. Nígbà tí ó bá sọ̀kalẹ̀ sí gbàgede wọn, òwúrọ̀ ọjọ́ náà yó sì burú fún àwọn ẹni-akìlọ̀-fún. 178. Kúrò lọ́dọ̀ wọn títí di ìgbà kan ná. 179. Àti pé máa wò wọ́n níran ná, àwọn náà ń bọ̀ wá ríran wò. 180. Mímọ́ ni fún Olúwa rẹ, Olúwa (tó ni) agbára, tayọ ohun tí wọ́n ń fi ròyìn (Rẹ̀). 181. Kí àlàáfíà máa bá àwọn Òjíṣẹ́ 182. Gbogbo ẹyìn ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa gbogbo ẹ̀dá.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute