Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
037

As-Saffat 37:66 فانهم لاكلون منها فماليون منها البطون ٦٦

37:66
فَإِنَّهُمۡ
لَأٓكِلُونَ
مِنۡهَا
فَمَالِـُٔونَ
مِنۡهَا
ٱلۡبُطُونَ
٦٦
Dájúdájú wọn yóò máa jẹ nínú rẹ̀. Wọ́n sì máa jẹ ẹ́ ní àjẹyo bámúbámú.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Tree of Zaqqum and its Companions

Here Allah asks: `Is that which He has mentioned of the delights of Paradise with its food, drink, companions and other joys better entertainment, or

أَمْ شَجَرَةُ الزَّقُّومِ

(or the tree of Zaqqum) which is in Hell' The meaning here is a specific kind of tree whi

…

The Tree of Zaqqum and its Companions

Here Allah asks: `Is that which He has mentioned of the delights of Paradise with its food, drink, companions and

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 37, Page 448, Juz 23

62. Ǹjẹ́ ìyẹn l’ó lóore jùlọ ní ibùdésí ni tàbí igi zaƙūm (igi ẹlẹ́gùn-ún)? 63. Dájúdájú Àwa ṣe é ní àdánwò fún àwọn alábòsí. 64. Dájúdájú òhun ni igi kan tí ó máa hù jáde láti ìdí iná Jẹhīm. 65. Èso rẹ̀ dà bí orí àwọn aṣ-Ṣaetọ̄n. 66. Dájúdájú wọn yóò máa jẹ nínú rẹ̀. Wọ́n sì máa jẹ ẹ́ ní àjẹyo bámúbámú. 67. Lẹ́yìn náà, dájúdájú wọn yóò mu àwọnúwẹ̀jẹ̀ olómi gbígbóná tó gbóná parí lé e lórí. 68. Lẹ́yìn náà, dájúdájú ibùpadàsí wọn ni iná Jẹhīm. 69. Dájúdájú wọ́n bá àwọn bàbá wọn ní olùṣìnà. 70. Àwọn náà sì ń yára tẹ̀lé orípa wọn. 71. Dájúdájú ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ ti ṣìnà ṣíwájú wọn. 72. Dájúdájú A ti rán àwọn olùkìlọ̀ sí wọn. 73. Nítorí náà, wo bí àtubọ̀tán àwọn ẹni-akìlọ̀-fún ti rí. 74. Àfi àwọn ẹrúsìn Allāhu, àwọn tí A ṣà lẹ́ṣà (fún ìgbàgbọ́ òdodo).

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute