Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
037

As-Saffat 37:87 فما ظنكم برب العالمين ٨٧

37:87
فَمَا
ظَنُّكُم
بِرَبِّ
ٱلۡعَٰلَمِينَ
٨٧
Kí sì ni èrò ọkàn yín sí Olúwa gbogbo ẹ̀dá?”1
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Story of Ibrahim and His People

`Ali bin Abi Talhah reported that Ibn `Abbas, may Allah be pleased with him:

وَإِنَّ مِن شِيعَتِهِ لإِبْرَهِيمَ

(And verily, among those who followed his ways was Ibrahim.) means, he was one of the followers of his religion. Mujahid said, "He was following his path

…

The Story of Ibrahim and His People

`Ali bin Abi Talhah reported that Ibn `Abbas, may Allah be pleased with him:

وَإِنَّ مِن شِيعَتِهِ لإِبْرَهِيمَ

(And

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 37, Page 449, Juz 23

83. Dájúdájú (Ànábì) ’Ibrọ̄hīm wà nínú ìjọ (tí ó tẹ̀lé ìlànà) rẹ̀. 84. (Ẹ rántí) nígbà tí ó dojú kọ Olúwa rẹ̀ pẹ̀lú ọkàn mímọ́. 85. (Rántí) nígbà tí ó sọ fún bàbá rẹ̀ àti àwọn ènìyàn rẹ̀ pé: "Kí ni ẹ̀ ń jọ́sìn fún? 86. Ṣé ẹ̀ ń gbèrò láti sọ irọ́ di ọlọ́hun lẹ́yìn Allāhu? 87. Kí sì ni èrò ọkàn yín sí Olúwa gbogbo ẹ̀dá?” 88. Ó ṣíjú wo àwọn ìràwọ̀ ní wíwò kan. 89. Ó sì sọ pé: “Dájúdájú ó rẹ̀ mí.” 90. Nítorí náà, wọ́n pa á tì, wọ́n sì lọ. 91. Nígbà náà, ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn òrìṣà wọn. Ó sì sọ pé: “Ṣé ẹ kò níí jẹun ni? 92. Kí ni ó ṣe yín tí ẹ kò sọ̀rọ̀?” 93. Nígbà náà, ó dojú lílù kọ wọ́n pẹ̀lú ọwọ́ ọ̀tún (ó sì rún wọn wómúwómú). 94. (Àwọn abọ̀rìṣà) sáré wá dojú kọ ọ́. 95. Ó sọ pé: “Ṣé ẹ óò máa jọ́sìn fún n̄ǹkan tí ẹ gbẹ́ kalẹ̀ lére ni? 96. Allāhu l’Ó sì dá ẹ̀yin àti n̄ǹkan tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́.” 97. Wọ́n wí pé: “Ẹ mọ ilé kan fún un, kí ẹ sì jù ú sínú iná.” 98. Wọ́n gbèrò ète sí i. A sì sọ wọ́n di ẹni yẹpẹrẹ.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute