Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
026

Ash-Shu'ara 26:198 ولو نزلناه على بعض الاعجمين ١٩٨

26:198
وَلَوۡ
نَزَّلۡنَٰهُ
عَلَىٰ
بَعۡضِ
ٱلۡأَعۡجَمِينَ
١٩٨
Tí ó bá jẹ́ pé A sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún apá kan àwọn elédè mìíràn ni,
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Qur'an was mentioned in the Previous Scriptures

Allah says: this Qur'an was mentioned and referred to in the previous Scriptures that were left behind by their Prophets who foretold it in ancient times and more recently. Allah took a covenant from them that they would follow it, and the last of t

…

The Qur'an was mentioned in the Previous Scriptures

Allah says: this Qur'an was mentioned and referred to in the previous Scriptures that were left beh

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 26, Page 375, Juz 19

192. Dájúdájú al-Ƙur’ān, wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ ni láti ọ̀dọ̀ Olúwa gbogbo ẹ̀dá. 193. Mọlāika Jibrīl, olùfọkàntán l’ó sọ̀ ọ́ kalẹ̀ 194. sínú ọkàn rẹ nítorí kí o lè wà nínú àwọn olùkìlọ̀ 195. pẹ̀lú èdè Lárúbáwá pọ́nńbélé. 196. Dájúdájú (ọ̀rọ̀ nípa rẹ̀) wà nínú ìpín-ìpín Tírà àwọn ẹni àkọ́kọ́. 197. Ṣé kò jẹ́ àmì kan fún wọn pé àwọn onímọ̀ (nínú) àwọn ọmọ ’Isrọ̄’īl nímọ̀ (sí àsọọ́lẹ̀ nípa) rẹ̀ (nínú tírà ọwọ́ wọn)? 198. Tí ó bá jẹ́ pé A sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún apá kan àwọn elédè mìíràn ni, 199. tí ó sì ké e fún wọn, wọn kò níí gbà á gbọ́ ní òdodo. 200. Báyẹn ni A ṣe mú (àtakò) wọ inú ọkàn àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀. 201. Wọn kò níí gbà á gbọ́ ní òdodo títí wọn yóò fi rí ìyà ẹlẹ́ta-eléro. 202. (Ìyà náà) yóò dé bá wọn ní òjijì; wọn kò sì níí fura. 203. Nígbà náà ni wọn yóò wí pé: “Ǹjẹ́ wọ́n lè lọ́ wa lára bí?” 204. Ṣé ìyà Wa ni wọ́n ń wá pẹ̀lú ìkánjú? 205. Sọ fún Mi tí A bá fún wọn ní ìgbádùn ayé fún ọdún gbọọrọ! 206. Lẹ́yìn náà, kí ohun tí À ń ṣe ní ìlérí fún wọn dé bá wọn. 207. Ohun tí A ṣe ní ìgbádùn fún wọn kò sì níí rọ̀ wọ́n lọ́rọ̀.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute