Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
026

Ash-Shu'ara 26:217 وتوكل على العزيز الرحيم ٢١٧

26:217
وَتَوَكَّلۡ
عَلَى
ٱلۡعَزِيزِ
ٱلرَّحِيمِ
٢١٧
Kí o sì gbáralé Alágbára, Àṣàkẹ́-ọ̀run;
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

The Command to warn His Tribe of near Kindred

Here Allah commands (His Prophet ) to worship Him alone, with no partner or associate, and tells him that whoever associates others in worship with Him, He will punish them. Then Allah commands His Messenger to warn his tribe of near kindred, i.e., those

…

The Command to warn His Tribe of near Kindred

Here Allah commands (His Prophet ) to worship Him alone, with no partner or associate, and tells him that

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 26, Page 376, Juz 19

208. A ò sì pa ìlú kan run àfi kí wọ́n ti ní àwọn olùkìlọ̀. 209. Ìrántí (dé fún wọn sẹ́). Àti pé Àwa kì í ṣe alábòsí. 210. Kì í ṣe àwọn aṣ-ṣaetọ̄n ni wọ́n sọ (al-Ƙur’ān) kalẹ̀. 211. Kò yẹ fún wọn. Wọn kò sì lágbára rẹ̀. 212. Dájúdájú A ti mú wọn takété sí gbígbọ́ rẹ̀ (láti ojú sánmọ̀). 213. Nítorí náà, má ṣe pe ọlọ́hun mìíràn mọ́ Allāhu, nítorí kí ìwọ má baà wà nínú àwọn tí A máa jẹ níyà. 214. Kí o sì kìlọ̀ fún àwọn ẹbí rẹ tó súnmọ́ jùlọ. 215. Kí o sì rẹ apá rẹ nílẹ̀ fún àwọn tó tẹ̀lé ọ nínú àwọn onígbàgbọ́ òdodo. 216. Tí wọ́n bá sì yapa (àṣẹ) rẹ, sọ pé: “Dájúdájú èmi yọwọ́ yọsẹ̀ nínú ohun tí ẹ̀ ń ṣe (níṣẹ́ aburú).” 217. Kí o sì gbáralé Alágbára, Àṣàkẹ́-ọ̀run; 218. Ẹni tó ń rí ọ nígbà tí ò ń dìde nàró (fún ìrun kíkí) 219. àti ìyírapadà rẹ (fún rukuu àti ìforíkanlẹ̀) láààrin àwọn olùforíkanlẹ̀. 220. Dájúdájú Òun mà ni Olùgbọ́, Onímọ̀.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute