Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
081

At-Takwir 81:9 باي ذنب قتلت ٩

81:9
بِأَيِّ
ذَنۢبٖ
قُتِلَتۡ
٩
ẹ̀ṣẹ̀ wo ni wọ́n pa òun fún,
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

What has been narrated about This Surah

Imam Ahmad recorded from Ibn `Umar that the Messenger of Allah ﷺ said,

«مَنْ سَرَّهُ أَنْ يَنْظُرَ إِلى يَوْمِ الْقِيَامَةِ كَأَنَّهُ رَأْيُ عَيْنٍ فَلْيَقْرَأْ:

إِذَا الشَّمْسُ كُوِّرَتْ

و

إِذَا السَّمَآءُ انفَطَرَتْ

و

إِذَا السَّمَآءُ ان

…

Which was revealed in Makkah

What has been narrated about This Surah

Imam Ahmad recorded from Ibn `Umar that the Messenger of Allah ﷺ said,

«مَنْ سَرَّهُ

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 81, Page 586, Juz 30

1. Nígbà tí wọ́n bá ká òòrùn kóróbójó dànù, 2. àti nígbà tí àwọn ìràwọ̀ bá já bọ́ káàkiri, 3. àti nígbà tí wọ́n bá mú àwọn àpáta rìn (kúrò ní àyè wọn, tí wọ́n kù wọ́n dànù), 4. àti nígbà tí wọ́n bá pa àwọn ràkúnmí aboyún tì, 5. àti nígbà tí wọ́n bá ko àwọn ẹranko jọ, 6. àti nígbà tí wọ́n bá mú àwọn agbami odò gbiná, 7. àti nígbà tí wọ́n bá so àwọn ẹ̀mí pọ̀ mọ́ra wọn, (ẹni rere pẹ̀lú ẹni rere, ẹni ibi pẹ̀lú ẹni ibi) 8. àti nígbà tí ọmọbìnrin tí wọ́n bò mọ́lẹ̀ láàyè bá bèèrè pé 9. ẹ̀ṣẹ̀ wo ni wọ́n pa òun fún, 10. àti nígbà tí wọ́n bá ṣí àwọn tákàdá (iṣẹ́ ẹ̀dá) sílẹ̀, 11. àti nígbà tí wọ́n bá ká sánmọ̀ kúrò lókè, 12. àti nígbà tí wọ́n bá mú iná Jẹhīm jò fòfò, 13. àti nígbà tí wọ́n bá sún Ọgbà Ìdẹ̀ra mọ́ (àwọn onígbàgbọ́ òdodo), 14. (nígbà náà ni) ẹ̀mí (kọ̀ọ̀kan) yóò mọ ohun tí ó mú wá (nínú iṣẹ́ ire àti iṣẹ́ ibi).

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute