Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
052

At-Tur 52:5 والسقف المرفوع ٥

52:5
وَٱلسَّقۡفِ
ٱلۡمَرۡفُوعِ
٥
Ó tún fi àjà tí wọ́n gbé sókè (ìyẹn, sánmọ̀) búra.
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Which was revealed in Makkah

The Virtues of Surat At-Tur

Malik narrated that Jubayr bin Mut`im said, "I heard the Prophet reciting Surat At-Tur while praying Maghrib. Surely, I have never heard a more beautiful voice or recitation than his recitation." This Hadith is recorded in the Two Sahihs using a

…

Which was revealed in Makkah

The Virtues of Surat At-Tur

Malik narrated that Jubayr bin Mut`im said, "I heard the Prophet reciting Surat At-Tur while pr

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 52, Page 523, Juz 27

1. Allāhu fi àpáta Tūr búra. 2. Ó tún fi Tírà tí wọ́n kọ n̄ǹkan sínú rẹ̀ búra . 3. (Wọ́n kọ̀ ọ́) sínú n̄ǹkan ìkọ̀wé tí wọ́n tẹ́ ojú rẹ̀ sílẹ̀. 4. Allāhu fi Ilé tí àwọn mọlāika ń wọnú rẹ̀ ní ojoojúmọ́ nínú sánmọ̀ búra. 5. Ó tún fi àjà tí wọ́n gbé sókè (ìyẹn, sánmọ̀) búra. 6. Ó tún fi agbami odò tí wọ́n máa mú iná jáde nínú rẹ̀ búra. 7. Dájúdájú ìyà Olúwa rẹ máa ṣẹlẹ̀. 8. Kò sí ẹni tí ó máa dènà rẹ̀. 9. (Ó máa ṣẹlẹ̀) ní ọjọ́ tí sánmọ̀ máa mì tìtì tààrà. 10. àpáta sì máa rìn lọ dànù. 11. Ní ọjọ́ yẹn, ègbé ni fún àwọn tó pe òdodo ní irọ́, 12. àwọn tí wọ́n wà nínú ìsọkúsọ, tí wọ́n ń ṣeré. 13. (Rántí) ọjọ́ tí wọn yóò máa tì wọ́n lọ́ sínú iná Jahanamọ ní ìtìkutì. 14. Èyí ni Iná náà tí ẹ̀ ń pè ní irọ́. 15. Ṣé idán ni èyí ni tàbí ẹ̀yin kò ríran? 16. Ẹ wọ inú rẹ̀ lọ. Ẹ fara dà á tàbí ẹ kò fara dà á, bákan náà ni fún yín. Ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ ni A óò fi san yín ní ẹ̀san.

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute