Az-Zumar 39:67 وما قدروا الله حق قدره والارض جميعا قبضته يوم القيامة والسماوات مطويات بيمينه سبحانه وتعالى عما يشركون ٦٧
وَمَا
قَدَرُواْ
ٱللَّهَ
حَقَّ
قَدۡرِهِۦ
وَٱلۡأَرۡضُ
جَمِيعٗا
قَبۡضَتُهُۥ
يَوۡمَ
ٱلۡقِيَٰمَةِ
وَٱلسَّمَٰوَٰتُ
مَطۡوِيَّٰتُۢ
بِيَمِينِهِۦۚ
سُبۡحَٰنَهُۥ
وَتَعَٰلَىٰ
عَمَّا
يُشۡرِكُونَ
٦٧
Wọn kò bu iyì fún Allāhu bí ó ṣe tọ́ láti bu iyì fún Un. Gbogbo ilẹ̀ pátápátá sì ni (Allāhu) máa fọwọ́ ara Rẹ̀ gbámú ní Ọjọ́ Àjíǹde. Ó sì máa fi ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ ká àwọn sánmọ̀ kóróbójó. Mímọ́ ni fún Un. Ó sì ga tayọ n̄ǹkan tí wọ́n ń fi ṣẹbọ sí I.
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
The Idolators did not make a just Estimate of Allah such as is due to Him
وَمَا قَدَرُواْ اللَّهَ حَقَّ قَدْرِهِ
(They made not a just estimate of Allah such as is due to Him.) means, the idolators did not give Allah His due when they worshipped others alongside Him. He is the Almighty, and there is n
…The Idolators did not make a just Estimate of Allah such as is due to Him
وَمَا قَدَرُواْ اللَّهَ حَقَّ قَدْرِهِ
(They made not a just estimate of Allah
…