Ibrahim 14:1 الر كتاب انزلناه اليك لتخرج الناس من الظلمات الى النور باذن ربهم الى صراط العزيز الحميد ١
الٓرۚ
كِتَٰبٌ
أَنزَلۡنَٰهُ
إِلَيۡكَ
لِتُخۡرِجَ
ٱلنَّاسَ
مِنَ
ٱلظُّلُمَٰتِ
إِلَى
ٱلنُّورِ
بِإِذۡنِ
رَبِّهِمۡ
إِلَىٰ
صِرَٰطِ
ٱلۡعَزِيزِ
ٱلۡحَمِيدِ
١
’Alif lām rọ̄. (Allāhu ló mọ ohun tí Ó gbàlérò pẹ̀lú àwọn háràfí náà.)1 (Èyí ni) Tírà kan tí A sọ̀kalẹ̀ fún ọ nítorí kí o lè mú àwọn ènìyàn kúrò láti inú àwọn òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ pẹ̀lú ìyọ̀ǹda Olúwa wọn. (Wọn yó sì bọ́) sí ọ̀nà Alágbára, Ọlọ́pẹ́ (tí ọpẹ́ tọ́ sí),
Read Tafsir
Ibn Kathir (Abridged)
Which was revealed in Makkah
(بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ )
In the Name of Allah, the Most Gracious, the Most Merciful.
Describing the Qur'an and warning Those Who defy it
Previously we discussed the meaning of the separate letters that appear in the beginnings of some Surahs.
كِتَابٌ أَنزَلْن
…Which was revealed in Makkah
(بِسْمِ اللَّهِ الرَّحْمَـنِ الرَّحِيمِ )
In the Name of Allah, the Most Gracious, the Most Merciful.