Sign in
Sign in
Sign in
Select Language
012

Yusuf 12:60 فان لم تاتوني به فلا كيل لكم عندي ولا تقربون ٦٠

12:60
فَإِن
لَّمۡ
تَأۡتُونِي
بِهِۦ
فَلَا
كَيۡلَ
لَكُمۡ
عِندِي
وَلَا
تَقۡرَبُونِ
٦٠
Tí ẹ ò bá sì mú un wá, kò sí (ẹrù oúnjẹ) wíwọ̀n fún yín lọ́dọ̀ mi. Kí ẹ sì má ṣe súnmọ́ mi.”
Continue Reading

Read Tafsir

Ibn Kathir (Abridged)

Yusuf's Brothers travel to Egypt

As-Suddi, Muhammad bin Ishaq and several others said that the reason why Yusuf's brothers went to Egypt, is that after Yusuf became minister of Egypt and the seven years of abundance passed, then came the seven years of drought that struck all areas of Egypt. The drou

…

Yusuf's Brothers travel to Egypt

As-Suddi, Muhammad bin Ishaq and several others said that the reason why Yusuf's brothers went to Egypt, is that after

…
More Tafsirs

Read in Context

Chapter 12, Page 242, Juz 13

58. Àwọn ọbàkan (Ànábì) Yūsuf dé, wọ́n sì wọlé tọ̀ ọ́. Ó dá wọn mọ̀. Àwọn kò sì mọ̀ ọ́n mọ́. 59. Nígbà tí ó sì fún wọn ní ẹrù oúnjẹ wọn tán, ó sọ pé: “Ẹ lọ mú ọbàkan yín wá láti ọ̀dọ̀ bàbá yín. Ṣé ẹ kò rí i pé dájúdájú mò ń wọn kóńgò ní ẹ̀kún rẹ́rẹ́ ni? Èmi sì dára jùlọ nínú àwọn olùgbàlejò. 60. Tí ẹ ò bá sì mú un wá, kò sí (ẹrù oúnjẹ) wíwọ̀n fún yín lọ́dọ̀ mi. Kí ẹ sì má ṣe súnmọ́ mi.” 61. Wọ́n sọ pé: “A máa jírẹ̀ẹ́bẹ̀ fún bàbá rẹ̀ láti gbà á lọ́wọ́ rẹ̀. Dájúdájú àwa máa ṣe bẹ́ẹ̀.” 62. Ó sì sọ fún àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé: “Ẹ fi owó-ọjà wọn sínú ẹrù (oúnjẹ) wọn nítorí kí wọ́n lè mọ̀ nígbà tí wọ́n bá padà dé ọ̀dọ̀ ará ilé wọ́n (pé a ti dá a padà fún wọn), wọn yó sì lè padà wá.”

- Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Notes and Reflections

You do not have any notes or reflections on this verse.

Notes placeholders

Stay Connected to the Quran ❤️

Short meaningful reminders to reset, reflect and stay connected to the Quran.

Read, Listen, Search, and Reflect on the Quran

Quran.com is a trusted platform used by millions worldwide to read, search, listen to, and reflect on the Quran in multiple languages. It provides translations, tafsir, recitations, word-by-word translation, and tools for deeper study, making the Quran accessible to everyone.

As a Sadaqah Jariyah, Quran.com is dedicated to helping people connect deeply with the Quran. Supported by Quran.Foundation, a 501(c)(3) non-profit organization, Quran.com continues to grow as a free and valuable resource for all, Alhamdulillah.

Navigate
Home
Quran Radio
Reciters
About Us
Developers
Product Updates
Feedback
Help
Donate
Our Projects
Quran.com
Quran For Android
Quran iOS
QuranReflect.com
Quran.AI
Sunnah.com
Nuqayah.com
Legacy.Quran.com
Corpus.Quran.com
Non-profit projects owned, managed, or sponsored by Quran.Foundation
Popular Links
Duas from the Quran
Quran Verse of the Day
Ayatul Kursi
Yaseen
Al Mulk
Ar-Rahman
Al Waqi'ah
Al Kahf
Al Muzzammil
SitemapPrivacyTerms and Conditions
© 2026 Quran.com. All Rights Reserved
Contribute